Bib sou entènèt

- Piblisite -




Joẹli 1:2 - Bibeli Mimọ

2 Gbọ́ eyi, ẹnyin arugbo, si fi eti silẹ, gbogbo ẹnyin ará ilẹ na. Eyi ha wà li ọjọ nyin, tabi li ọjọ awọn baba nyin?

Gade chapit la Kopi

Yoruba Bible

2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin àgbà, ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ yìí! Ǹjẹ́ irú ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ti ṣẹlẹ̀ rí ní àkókò yín, tabi ní àkókò àwọn baba yín?

Gade chapit la Kopi

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

2 Ẹ gbọ́ èyí ẹ̀yin àgbàgbà; ẹ fi etí sílẹ̀ gbogbo ẹ̀yin ènìyàn ará ilẹ̀ náà. Ǹjẹ́ irú èyí ha wà ní ọjọ́ yín, tàbí ní ọjọ́ àwọn baba yín?

Gade chapit la Kopi




Joẹli 1:2

Swiv nou:

Piblisite


Piblisite