22 òbúkọ kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀.
22 Akọ ewurẹ kan fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ;
22 Akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;
akọ mààlúù kékeré kan, àgbò kan ati ọ̀dọ́ àgbò kan, ọlọ́dún kan, fún ẹbọ sísun;
Ó sì mú akọ mààlúù meji, àgbò marun-un, òbúkọ marun-un ati ọ̀dọ́ àgbò marun-un ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan wá fún ẹbọ alaafia. Wọ́n jẹ́ ọrẹ Netaneli ọmọ Suari.
nígbà tí wọ́n bá fi ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá yìí hàn án, yóo mú òbúkọ kan tí kò ní àbààwọ́n wá, yóo fi rúbọ.