Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 7:16 - Yoruba Bible

16 ati òbúkọ kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

16 Akọ ewurẹ kan fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 Akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 7:16
3 Iomraidhean Croise  

nígbà tí wọ́n bá fi ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá yìí hàn án, yóo mú òbúkọ kan tí kò ní àbààwọ́n wá, yóo fi rúbọ.


Alufaa yóo ti ìka bọ inú ẹ̀jẹ̀ ẹran tí wọ́n fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ yìí yóo fi sí ara àwọn ìwo pẹpẹ ẹbọ sísun; yóo sì da ẹ̀jẹ̀ yòókù sílẹ̀ nídìí pẹpẹ.


akọ mààlúù kékeré kan, àgbò kan, ọ̀dọ́ àgbò kan, ọlọ́dún kan, fún ẹbọ sísun;


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan