Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 4:41 - Yoruba Bible

41 Èyí ni iye àwọn tí Mose ati Aaroni kà ninu àwọn ọmọ Geriṣoni tí wọ́n lè ṣiṣẹ́ ninu Àgọ́ Àjọ gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

41 Wọnyi li awọn ti a kà ni idile awọn ọmọ Gerṣoni, gbogbo awọn ti o ṣe iṣẹ-ìsin ninu agọ́ ajọ, ti Mose ati Aaroni kà gẹgẹ bi aṣẹ OLUWA.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

41 Èyí jẹ́ àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Gerṣoni, àwọn tó ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé. Mose àti Aaroni ṣe bí àṣẹ Olúwa.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 4:41
4 Iomraidhean Croise  

Mose sì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.


jẹ́ ẹgbẹtala ó lé ọgbọ̀n (2,630).


Àwọn tí a kà ninu àwọn ọmọ Merari, ní ìdílé-ìdílé gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn,


Mose ka àwọn eniyan náà, ó sì yan iṣẹ́ fún olukuluku wọn gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún un.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan