Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 4:22 - Yoruba Bible

22 “Ka iye àwọn ọmọ Geriṣoni ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

22 Kà iye awọn ọmọ Gerṣoni pẹlu, gẹgẹ bi ile baba wọn, nipa idile wọn;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

22 “Tún ka iye àwọn ọmọ Gerṣoni nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 4:22
5 Iomraidhean Croise  

Orúkọ àwọn ọmọ Geriṣoni ni Libini ati Ṣimei.


Geriṣoni ni baba ńlá àwọn ọmọ Libini ati àwọn ọmọ Ṣimei.


Eliasafu ọmọ Laeli ni yóo jẹ́ olórí wọn.


OLUWA sọ fún Mose pé,


ka àwọn ọkunrin wọn láti ẹni ọgbọ̀n ọdún títí dé aadọta, àwọn tí wọ́n lè ṣiṣẹ́ ninu Àgọ́ Àjọ.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan