Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 4:2 - Yoruba Bible

2 “Ẹ ka iye àwọn ọmọ Kohati láàrin àwọn ọmọ Lefi, ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

2 Kà iye awọn ọmọ Kohati kuro ninu awọn ọmọ Lefi, nipa idile wọn, ile baba wọn,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

2 “Ka iye àwọn ọmọ Kohati láàrín àwọn ọmọ Lefi nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 4:2
4 Iomraidhean Croise  

Orúkọ àwọn ọmọ Kohati ni Amramu, Iṣari, Heburoni ati Usieli.


Kohati ni baba ńlá àwọn ọmọ Amramu ati àwọn ọmọ Iṣari, àwọn ọmọ Heburoni ati àwọn ọmọ Usieli.


OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé:


Kí ẹ ka àwọn ọkunrin wọn, láti ẹni ọgbọ̀n ọdún títí dé aadọta, àwọn tí wọ́n lè ṣiṣẹ́ ninu Àgọ́ Àjọ.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan