Numeri 32:8 - Yoruba Bible8 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn baba yín ṣe nígbà tí mo rán wọn láti Kadeṣi Banea láti lọ ṣe amí ilẹ̀ náà. Faic an caibideilBibeli Mimọ8 Bẹ̃li awọn baba nyin ṣe, nigbati mo rán wọn lati Kadeṣi-barnea lọ lati wò ilẹ na. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Èyí ni nǹkan tí baba yín ṣe nígbà tí mo rán wọn láti Kadeṣi-Barnea láti lọ wo ilẹ̀ náà. Faic an caibideil |