Numeri 3:18 - Yoruba Bible18 Orúkọ àwọn ọmọ Geriṣoni ni Libini ati Ṣimei. Faic an caibideilBibeli Mimọ18 Wọnyi si ni orukọ awọn ọmọ Gerṣoni gẹgẹ bi idile wọn; Libni ati Ṣimei. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní18 Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei. Faic an caibideil |