Numeri 27:5 - Yoruba Bible5 Mose bá bá OLUWA sọ̀rọ̀ nípa wọn, Faic an caibideilBibeli Mimọ5 Mose si mú ọ̀ran wọn wá siwaju OLUWA. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní5 Nígbà náà Mose mú ọ̀rọ̀ wọn wá síwájú Olúwa. Faic an caibideil |
Wọ́n tọ Eleasari, alufaa, ati Joṣua ọmọ Nuni, ati àwọn àgbààgbà lọ, wọ́n wí fún wọn pé, “OLUWA ti pàṣẹ fún Mose pé kí ó pín ilẹ̀ fún àwa náà, gẹ́gẹ́ bí ó ti pín fún àwọn ìbátan wa, tí wọ́n jẹ́ ọkunrin.” Nítorí náà bí OLUWA ti pa á láṣẹ, wọ́n pín ilẹ̀ fún àwọn náà gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti pín fún àwọn ìbátan wọn tí wọ́n jẹ́ ọkunrin.