Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 26:23 - Yoruba Bible

23 Àwọn ọmọ Isakari ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Tola, ìdílé Pua;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

23 Awọn ọmọ Issakari gẹgẹ bi idile wọn: ti Tola, idile Tola: ti Pufa, idile Pufa:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

23 Àwọn ọmọ Isakari gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Tola, ìdílé Tola; ti Pufa, ìdílé Pufa;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 26:23
6 Iomraidhean Croise  

Àwọn ọmọ ti Isakari ni: Tola, Pua, Jobu ati Ṣimironi.


Àwọn mẹrin ni ọmọ Isakari: Tola, Pua, Jaṣubu ati Ṣimironi.


Ninu ẹ̀yà Isakari, àwọn tí wọ́n tó ẹni ogún ọdún, tí wọ́n tó lọ sójú ogun, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn ní ìdílé-ìdílé


Kí ẹ̀yà Isakari pàgọ́ tẹ̀lé ẹ̀yà Juda; Netaneli ọmọ Suari ni yóo jẹ́ olórí wọn.


ìdílé Jaṣubu ati ìdílé Ṣimironi.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan