16 ìdílé Osini, ati ìdílé Eri;
16 Ti Osni, idile Osni: ti Eri, idile Eri:
16 ti Osni, ìdílé Osni; ti Eri, ìdílé Eri;
Àwọn ọmọ ti Gadi ni: Sifioni, Hagi, Ṣuni, Esiboni, Eri, Arodu, ati Areli.
Àwọn ọmọ Gadi ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Sefoni, ìdílé Hagi, ati ìdílé Ṣuni;
ìdílé Arodu ati ìdílé Areli.