Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 21:12 - Yoruba Bible

12 Wọ́n gbéra láti ibẹ̀, wọ́n lọ pa àgọ́ sí àfonífojì Seredi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

12 Lati ibẹ̀ lọ nwọn ṣí, nwọn si dó si afonifoji Seredi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti gbéra wọ́n sì pa ibùdó ní Àfonífojì Seredi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 21:12
4 Iomraidhean Croise  

Lẹ́yìn tí wọ́n kúrò ní Obotu wọ́n pa àgọ́ sí Òkè-Abarimu ní aṣálẹ̀ tí ó wà níwájú Moabu, ní ìhà ìlà oòrùn.


Láti Iyimu wọ́n lọ sí Diboni Gadi.


“Ẹ dìde, ẹ bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò yín, kí ẹ sì ré àfonífojì Anoni kọjá. Mo ti fi Sihoni, ọba Heṣiboni, ní ilẹ̀ àwọn ará Amori, le yín lọ́wọ́, àtòun ati ilẹ̀ rẹ̀. Ẹ bẹ̀rẹ̀ sí bá a jagun, kí ẹ sì máa gba ilẹ̀ rẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan