Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 21:11 - Yoruba Bible

11 Lẹ́yìn tí wọ́n kúrò ní Obotu wọ́n pa àgọ́ sí Òkè-Abarimu ní aṣálẹ̀ tí ó wà níwájú Moabu, ní ìhà ìlà oòrùn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

11 Nwọn si ṣi lati Obotu lọ, nwọn si dó si Iye-abarimu, li aginjù ti mbẹ niwaju Moabu, ni ìha ìla-õrùn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

11 Wọ́n gbéra ní Obotu wọ́n sì pa ibùdó sí Iye-Abarimu, ní aginjù tí ó kọjú sí Moabu ní ìdojúkọ ìlà-oòrùn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 21:11
4 Iomraidhean Croise  

Àwọn ọmọ Israẹli ṣí kúrò níbẹ̀, wọ́n pa àgọ́ wọn sí Obotu.


Wọ́n gbéra láti ibẹ̀, wọ́n lọ pa àgọ́ sí àfonífojì Seredi.


Láti Punoni wọ́n lọ sí Obotu.


Láti Obotu wọ́n lọ sí Òkè Abarimu ní agbègbè Moabu.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan