Numeri 2:6 - Yoruba Bible6 Àwọn ọmọ ogun tí a kà ninu wọn jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlọgbọn ó lé irinwo (54,400). Faic an caibideilBibeli Mimọ6 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹtadilọgbọ̀n o le irinwo. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó-lé-irínwó (54,400). Faic an caibideil |