Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 2:22 - Yoruba Bible

22 Ẹ̀yà Bẹnjamini ni yóo pàgọ́ tẹ̀lé ẹ̀yà Manase; Abidoni, ọmọ Gideoni ni yóo sì jẹ́ olórí wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

22 Ati ẹ̀ya Benjamini: Abidani ọmọ Gideoni yio si jẹ́ olori awọn ọmọ Benjamini:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

22 Ẹ̀yà Benjamini ni yóò tẹ̀lé e. Olórí Benjamini ni Abidani ọmọ Gideoni.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 2:22
7 Iomraidhean Croise  

Ẹ wo Bẹnjamini tí ó kéré jù níwájú, ẹ wo ogunlọ́gọ̀ àwọn ìjòyè Juda, ẹ wo àwọn ìjòyè Sebuluni ati ti Nafutali.


Abidani ọmọ Gideoni ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini.


Olórí ẹ̀yà Bẹnjamini sì ni Abidani ọmọ Gideoni.


Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaafa ó lé igba (32,200).


Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlogun ó lé egbeje (35,400).


Ní ọjọ́ kẹsan-an ni Abidani ọmọ Gideoni, olórí àwọn ẹ̀yà Bẹnjamini mú ọrẹ tirẹ̀ wá.


Abidani ọmọ Gideoni, kó akọ mààlúù meji, àgbò marun-un, òbúkọ marun-un, ati ọ̀dọ́ àgbò marun-un, ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan sílẹ̀ fún ẹbọ alaafia.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan