Numeri 2:11 - Yoruba Bible11 Àwọn ọmọ ogun tí a kà ninu wọ́n jẹ́ ẹgbaa mẹtalelogun ó lé ẹẹdẹgbẹta (46,500). Faic an caibideilBibeli Mimọ11 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹtalelogun o le ẹdẹgbẹta. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tàlélógún ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta. (46,500). Faic an caibideil |