Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 13:6 - Yoruba Bible

6 láti inú ẹ̀yà Juda, ó rán Kalebu, ọmọ Jefune;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

6 Ninu ẹ̀ya Juda, Kalebu ọmọ Jefunne.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 láti inú ẹ̀yà Juda, Kalebu ọmọ Jefunne;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 13:6
16 Iomraidhean Croise  

Kalebu, ọmọ Jefune, bí ọmọ mẹta: Iru, Ela, ati Naamu. Ela ni ó bí Kenasi.


Ṣugbọn Kalebu pa àwọn eniyan náà lẹ́nu mọ́ níwájú Mose, ó ní, “Ẹ jẹ́ kí á lọ nisinsinyii láti gba ilẹ̀ náà, nítorí a lágbára tó láti borí àwọn eniyan náà.”


láti inú ẹ̀yà Simeoni, ó rán Ṣafati ọmọ Hori;


láti inú ẹ̀yà Isakari, ó rán Igali, ọmọ Josẹfu;


Ṣugbọn nítorí pé iranṣẹ mi, Kalebu, ní ẹ̀mí tí ó yàtọ̀, ó sì jẹ́ olóòótọ́ sí mi, n óo mú un dé ilẹ̀ tí ó lọ wò, ilẹ̀ náà yóo sì jẹ́ ti àwọn ọmọ rẹ̀.


Ẹnikẹ́ni ninu yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo ti búra pé yóo jẹ́ ibùgbé yín, àfi Kalebu ọmọ Jefune ati Joṣua, ọmọ Nuni.


Joṣua ọmọ Nuni ati Kalebu ọmọ Jefune nìkan ni wọ́n yè ninu àwọn amí mejila náà.


Joṣua ọmọ Nuni ati Kalebu ọmọ Jefune tí wọ́n wà lára àwọn amí fa aṣọ wọn ya láti fi ìbànújẹ́ wọn hàn.


Nítorí pé OLUWA ti sọ pé gbogbo àwọn ti ìgbà náà ni yóo kú ninu aṣálẹ̀. Kalebu ọmọ Jefune ati Joṣua ọmọ Nuni nìkan ni ó kù lára wọn.


Àwọn olórí náà nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà Juda, a yan Kalebu ọmọ Jefune.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan