Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 13:13 - Yoruba Bible

13 láti inú ẹ̀yà Aṣeri, ó rán Seturu, ọmọ Mikaeli;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

13 Ninu ẹ̀ya Aṣeri, Seturu ọmọ Mikaeli.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 Láti inú ẹ̀yà Aṣeri, Seturu ọmọ Mikaeli.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 13:13
5 Iomraidhean Croise  

OLUWA sọ fún Mose pé,


láti inú ẹ̀yà Dani, ó rán Amieli, ọmọ Gemali;


láti inú ẹ̀yà Nafutali, ó rán Nahibi ọmọ Fofisi;


Gbogbo àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí ké, wọn sì fi gbogbo òru ọjọ́ náà sọkún.


“Gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun wa ti pàṣẹ fún wa nígbà náà, a gbéra ní Horebu, a sì la àwọn aṣálẹ̀ ńláńlá tí wọ́n bani lẹ́rù kọjá, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin náà ṣe rí i ní ojú ọ̀nà àwọn agbègbè olókè àwọn ará Amori; a sì dé Kadeṣi Banea.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan