Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 11:9 - Yoruba Bible

9 Òròòru ni mana náà máa ń bọ́ nígbà tí ìrì bá ń sẹ̀ ní ibùdó.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

9 Nigbati ìri ba si sẹ̀ si ibudó li oru, manna a bọ́ si i.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 Nígbà tí ìrì bá ẹ̀ sí ibùdó lórí ni manna náà máa ń bọ́ pẹ̀lú rẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 11:9
6 Iomraidhean Croise  

Wọ́n bèèrè ẹran, ó fún wọn ní àparò, ó sì pèsè oúnjẹ àjẹtẹ́rùn fún wọn láti ọ̀run.


Mose gbọ́ bí àwọn eniyan náà ti ń sọkún lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ wọn, olukuluku pẹlu àwọn ará ilé rẹ̀. Ọ̀rọ̀ náà dun Mose, ibinu OLUWA sì ru sí àwọn eniyan náà.


Àwọn eniyan náà a máa lọ kó wọn láàárọ̀, wọn á lọ̀ ọ́ tabi kí wọn gún un lódó láti fi ṣe ìyẹ̀fun. Wọn á sè é ninu ìkòkò, wọn á fi ṣe bíi àkàrà, adùn rẹ̀ sì dàbí ti àkàrà dídùn tí a fi òróró olifi dín.


Kí ẹ̀kọ́ mi kí ó máa rọ̀ bí òjò, àní, bí ọ̀wààrà òjò tíí dẹ ewébẹ̀ lọ́rùn; kí ó sì máa sẹ̀ bí ìrì, bí òjò wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́ tíí tu koríko lára.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan