Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 1:8 - Yoruba Bible

8 Netaneli ọmọ Suari ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Isakari.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

8 Ti Issakari; Netaneli ọmọ Suari.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

8 Láti ọ̀dọ̀ Isakari, Netaneli ọmọ Ṣuari;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 1:8
5 Iomraidhean Croise  

Naṣoni ọmọ Aminadabu ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Juda.


Eliabu ọmọ Heloni ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Sebuluni.


Netaneli ọmọ Suari ni olórí ẹ̀yà Isakari.


Kí ẹ̀yà Isakari pàgọ́ tẹ̀lé ẹ̀yà Juda; Netaneli ọmọ Suari ni yóo jẹ́ olórí wọn.


Ní ọjọ́ keji ni Netaneli ọmọ Suari olórí ẹ̀yà Isakari mú ọrẹ tirẹ̀ wá.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan