Numeri 1:6 - Yoruba Bible6 Ṣelumieli ọmọ Suriṣadai ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Simeoni. Faic an caibideilBibeli Mimọ6 Ti Simeoni; Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Láti ọ̀dọ̀ Simeoni, Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai; Faic an caibideil |