48 nítorí pé OLUWA ti sọ fún Mose pé,
48 Nitoripe OLUWA ti sọ fun Mose pe,
48 Nítorí Olúwa ti sọ fún Mose pé,
Ṣugbọn wọn kò ka àwọn ọmọ Lefi mọ́ wọn,
kí ó má ka ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ọmọ Israẹli nígbà tí ó bá ń kà wọ́n.