Numeri 1:43 - Yoruba Bible43 jẹ́ ẹgbaa mẹrindinlọgbọn ó lé egbeje (53,400). Faic an caibideilBibeli Mimọ43 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Naftali, o jẹ́ ẹgba mẹrindilọgbọ̀n o le egbeje. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní43 Iye àwọn tí a kà nínú ẹ̀yà Naftali jẹ́ ẹgbàá-mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ó-lé-egbèje (53,400). Faic an caibideil |