Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 1:42 - Yoruba Bible

42 Ninu ẹ̀yà Nafutali àwọn tí wọ́n tó ẹni ogún ọdún, tí wọ́n tó lọ sójú ogun, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn ní ìdílé-ìdílé

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

42 Ti awọn ọmọ Naftali, iran wọn, nipa idile wọn, nipa ile baba wọn, gẹgẹ bi iye orukọ, lati ẹni ogún ọdún lọ ati jù bẹ̃ lọ, gbogbo awọn ti o le jade lọ si ogun;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

42 Láti ìran Naftali: Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún ó lé, tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 1:42
6 Iomraidhean Croise  

Àwọn ọmọ ti Nafutali ni Jaseeli, Guni, Jeseri, ati Ṣilemu.


Nafutali dàbí àgbọ̀nrín tí ń sáré káàkiri, tí ó sì ní àwọn ọmọ tí ó lẹ́wà.


jẹ́ ọ̀kẹ́ meji le ẹẹdẹgbẹjọ (41,500).


jẹ́ ẹgbaa mẹrindinlọgbọn ó lé egbeje (53,400).


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan