Numeri 1:19 - Yoruba Bible19 Mose kà wọ́n ní ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu aṣálẹ̀ Sinai gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un. Faic an caibideilBibeli Mimọ19 Bi OLUWA ti paṣẹ fun Mose, bẹ̃li o si kaye wọn ni ijù Sinai. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní19 gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mose. Bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe kà wọ́n nínú aginjù Sinai. Faic an caibideil |