Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 1:15 - Yoruba Bible

15 Ahira ọmọ Enani ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Nafutali.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

15 Ti Naftali; Ahira ọmọ Enani.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 Láti ọ̀dọ̀ Naftali, Ahira ọmọ Enani.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 1:15
5 Iomraidhean Croise  

Eliasafu ọmọ Deueli ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Gadi.


Àwọn ni olórí tí a yàn ninu àwọn ọmọ Israẹli, olukuluku wọn jẹ́ olórí ninu ẹ̀yà wọn, ati ní ìdílé wọn.


Olórí ẹ̀yà Nafutali sì ni Ahira ọmọ Enani.


Lẹ́yìn náà ni ẹ̀yà Nafutali; Ahira, ọmọ Enani ni yóo jẹ́ olórí wọn.


Ní ọjọ́ kejila ni Ahira ọmọ Enani, olórí àwọn ẹ̀yà Nafutali, mú ọrẹ tirẹ̀ wá.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan