Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 1:14 - Yoruba Bible

14 Eliasafu ọmọ Deueli ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Gadi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

14 Ti Gadi; Eliasafu ọmọ Deueli.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

14 Láti ọ̀dọ̀ Gadi, Eliasafu ọmọ Deueli;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 1:14
5 Iomraidhean Croise  

Pagieli ọmọ Okirani ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Aṣeri.


Ahira ọmọ Enani ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Nafutali.


Olórí ẹ̀yà Gadi sì ni Eliasafu ọmọ Deueli.


Ẹ̀yà Gadi ni yóo pàgọ́ tẹ̀lé ẹ̀yà Simeoni; Eliasafu ọmọ Reueli ni yóo jẹ́ olórí wọn.


Ní ọjọ́ kẹfa ni Eliasafu, ọmọ Deueli, olórí àwọn ẹ̀yà Gadi, mú ọrẹ tirẹ̀ wá.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan