Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Marku 15:3 - Yoruba Bible

3 Àwọn olórí alufaa ń fi ẹ̀sùn pupọ kàn án.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

3 Awọn olori alufa si fi i sùn li ohun pipọ: ṣugbọn on ko dahùn kan.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Àwọn olórí àlùfáà fi ẹ̀sùn ohun púpọ̀ kàn án.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Marku 15:3
11 Iomraidhean Croise  

Àní, mo dàbí ẹni tí kò gbọ́rọ̀, tí kò sì ní àwíjàre kan lẹ́nu.


Wọ́n ni í lára, wọ́n pọ́n ọn lójú, sibẹsibẹ kò lanu sọ̀rọ̀, wọ́n fà á lọ bí ọ̀dọ́ aguntan tí wọn ń lọ pa, ati bí aguntan tíí yadi níwájú àwọn tí ń rẹ́ irun rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò lanu sọ̀rọ̀.


Ṣugbọn bí àwọn olórí alufaa ati àwọn àgbà ti ń fi ẹ̀sùn kàn án tó, kò fèsì rárá.


Pilatu bi Jesu pé, “Ṣé ìwọ ni ọba àwọn Juu?” Jesu dá a lóhùn pé, “O ti fi ẹnu ara rẹ sọ ọ́.”


Pilatu bá tún bi í pé, “O kò sì fèsì rárá? Ìwọ kò gbọ́ bí wọ́n ti ń fi oríṣìíríṣìí ẹ̀sùn kàn ọ́ ni?”


Ṣugbọn Jesu kò tún dá a lóhùn rárá mọ́, èyí mú kí ẹnu ya Pilatu.


Láti ìgbà náà ni Pilatu ti ń wá ọ̀nà láti dá Jesu sílẹ̀. Ṣugbọn àwọn Juu ń kígbe pé, “Bí o bá dá ọkunrin yìí sílẹ̀, ìwọ kì í ṣe ọ̀rẹ́ Kesari, gbogbo ẹni tí ó bá fi ara rẹ̀ jọba lòdì sí Kesari.”


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan