Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Marku 10:4 - Yoruba Bible

4 Wọ́n dáhùn pé, “Mose yọ̀ǹda pé kí ọkọ kọ ìwé ìkọ̀sílẹ̀ fún iyawo rẹ̀, kí ó sì kọ̀ ọ́.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

4 Nwọn si wipe, Mose yọda fun wa lati kọ iwe ikọsilẹ fun u, ki a si fi i silẹ.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

4 Wọ́n dáhùn pé, “Mose yọ̀ǹda fún wa láti kọ ìwé ìkọ̀sílẹ̀ fún un, kí a sì fi sílẹ̀.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Marku 10:4
7 Iomraidhean Croise  

OLUWA ní: OLUWA ní: “Ìwé ìkọ̀sílẹ̀ tí mo fi kọ àwọn eniyan mi sílẹ̀ dà? Ta ni mo tà yín fún, tí mo jẹ lówó? Ẹ wò ó! Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín ni a ṣe tà yín, nítorí àìdára yín ni mo ṣe kọ̀ yín sílẹ̀.


OLUWA ní, “Ṣé bí ọkọ bá kọ iyawo rẹ̀ sílẹ̀, tí iyawo náà sì kó jáde nílé ọkọ, tí ó lọ fẹ́ ẹlòmíràn, ṣé ọkọ rẹ̀ àkọ́kọ́ lè tún lọ gbà á pada? Ṣé ilẹ̀ náà kò ní di ìbàjẹ́? Lẹ́yìn tí ẹ ti ṣe àgbèrè pẹlu ọpọlọpọ olólùfẹ́; ẹ wá fẹ́ pada sọ́dọ̀ mi?


Eniyan rere ni Josẹfu ọkọ rẹ̀, kò fẹ́ dójú tì í, ó fẹ́ rọra kọ̀ ọ́ sílẹ̀ ní bòńkẹ́lẹ́.


Wọ́n bá tún bi í pé, “Kí ló dé tí Mose fi pàṣẹ pé kí ọkọ fún aya ní ìwé ìkọ̀sílẹ̀, kí ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀?”


Ó dá wọn lóhùn pé, “Kí ni Mose pa láṣẹ fun yín?”


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan