Luku 14:4 - Yoruba Bible4 Wọ́n bá dákẹ́. Jesu bá mú ọkunrin náà, ó wò ó sàn, ó bá ní kí ó máa lọ. Faic an caibideilBibeli Mimọ4 Nwọn si dakẹ. O si mu u, o mu u larada, o si jọwọ rẹ̀ lọwọ lọ; Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Wọ́n sì dákẹ́. Ó sì mú un, ó mú un láradá, ó sì jẹ́ kí ó lọ. Faic an caibideil |