Luku 14:2 - Yoruba Bible2 Ọkunrin kan wà níwájú rẹ̀ níbẹ̀ tí gbogbo ara rẹ̀ wú bòmù-bòmù. Faic an caibideilBibeli Mimọ2 Si kiyesi i, ọkunrin kan ti o li asunkun mbẹ niwaju rẹ̀. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 Sì kíyèsi i, ọkùnrin kan tí ó ní ara wíwú níwájú rẹ̀. Faic an caibideil |