Luku 10:12 - Yoruba Bible12 Mo sọ fun yín pé yóo sàn fún Sodomu ní ọjọ́ ńlá náà jù fún ìlú náà lọ. Faic an caibideilBibeli Mimọ12 Ṣugbọn mo wi fun nyin, yio san fun Sodomu ni ijọ na, jù fun ilu na lọ. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Ṣùgbọ́n mo wí fún yín, yóò sàn fún Sodomu ní ọjọ́ náà, ju fún ìlú náà lọ. Faic an caibideil |