Joṣua 4:16 - Yoruba Bible16 “Pàṣẹ fún àwọn alufaa tí wọ́n gbé Àpótí Ẹ̀rí pé kí wọ́n jáde kúrò ninu odò Jọdani.” Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Paṣẹ fun awọn alufa ti o rù apoti ẹri nì pe, ki nwọn ki o ti inu Jordani jade. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 “Pàṣẹ fún àwọn àlùfáà tí o ń ru àpótí ẹ̀rí, kí wọn kí ó jáde kúrò nínú odò Jordani.” Faic an caibideil |