Joṣua 4:1 - Yoruba Bible1 Nígbà tí gbogbo àwọn eniyan náà rékọjá sí òdìkejì odò Jọdani tán, OLUWA wí fún Joṣua pé, Faic an caibideilBibeli Mimọ1 O si ṣe, nigbati gbogbo awọn enia rekọja Jordani tán, ni OLUWA wi fun Joṣua pe, Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní1 Nígbà tí gbogbo orílẹ̀-èdè náà kọjá nínú odò Jordani tan, Olúwa sọ fún Joṣua pé, Faic an caibideil |