Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Joṣua 19:2 - Yoruba Bible

2 Àwọn ìlú tí ó wà ninu ilẹ̀ tí wọ́n pín fún wọn nìyí: Beeriṣeba, Ṣeba, Molada;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

2 Nwọn si ní Beeri-ṣeba, tabi Ṣeba, ati Molada, ni ilẹ-iní wọn;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

2 Lára ìpín wọn ní: Beerṣeba (tàbí Ṣeba), Molada,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Joṣua 19:2
8 Iomraidhean Croise  

Abrahamu bá dìde ní òwúrọ̀ kutukutu, ó mú oúnjẹ ati omi sinu ìgò aláwọ kan, ó dì wọ́n fún Hagari, ó kó wọn kọ́ ọ léjìká, ó fa ọmọ rẹ̀ lé e lọ́wọ́, ó ní kí wọn ó jáde kúrò nílé. Hagari jáde nílé, ó bá ń rìn káàkiri ninu aginjù Beeriṣeba.


Ìdí rẹ̀ nìyí tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní Beeriṣeba, nítorí pé níbẹ̀ ni àwọn mejeeji ti búra.


Amamu, Ṣema, Molada;


Hasari Ṣuali, Beeriṣeba, Bisiotaya;


Ilẹ̀ keji tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Simeoni, ilẹ̀ tiwọn bọ́ sí ààrin ìpín ti ẹ̀yà Juda.


Hasari Ṣuali, Bala, Esemu;


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan