Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 9:12 - Yoruba Bible

12 Wọ́n bi í pé, “Níbo ni ọkunrin náà wà?” Ó dáhùn pé, “Èmi kò mọ̀.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

12 Nwọn si wi fun u pe, On na ha dà? O wipe, emi kò mọ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Wọ́n sì wí fún un pé, “Òun náà ha dà?” Ó sì wí pé, “Èmi kò mọ̀.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 9:12
5 Iomraidhean Croise  

Àwọn Juu bẹ̀rẹ̀ sí wá a níbi àjọ̀dún náà, wọ́n ń bèèrè pé, “Níbo ni ó wà?”


Ó dá wọn lóhùn pé, “Ọkunrin tí wọn ń pè ní Jesu ni ó po amọ̀, tí ó fi lẹ̀ mí lójú, tí ó sọ fún mi pé kí n lọ bọ́jú ní adágún Siloamu. Mo lọ, mo bọ́jú, mo sì ríran.”


Àwọn kan bá mú ọkunrin tí ojú rẹ̀ ti fọ́ rí yìí lọ sọ́dọ̀ àwọn Farisi.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan