Johanu 8:57 - Yoruba Bible57 Àwọn Juu sọ fún un pé, “Ìwọ yìí ti rí Abrahamu, nígbà tí o kò ì tíì tó ẹni aadọta ọdún?” Faic an caibideilBibeli Mimọ57 Nitorina awọn Ju wi fun u pe, Ọdún rẹ kò ti ito adọta, iwọ si ti ri Abrahamu? Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní57 Nítorí náà, àwọn Júù wí fún un pé, “Ọdún rẹ kò ì tó àádọ́ta, ìwọ sì ti rí Abrahamu?” Faic an caibideil |