Johanu 8:4 - Yoruba Bible4 wọ́n wá sọ fún Jesu pé, “Olùkọ́ni, a ká obinrin yìí mọ́ ibi tí ó ti ń ṣe àgbèrè, a ká a mọ́ ọn gan-an ni! Faic an caibideilBibeli Mimọ4 Nwọn wi fun u pe, Olukọni, a mu obinrin yi ninu panṣaga, ninu ṣiṣe e pãpã. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Wọ́n sì wí fún un pé, “Olùkọ́, a mú obìnrin yìí nínú ìṣe panṣágà, Faic an caibideil |