Johanu 7:21 - Yoruba Bible21 Jesu dá wọn lóhùn pé, “Mo ṣe iṣẹ́ kan, ẹnu ya gbogbo yín. Faic an caibideilBibeli Mimọ21 Jesu dahùn o si wi fun wọn pe, Kìki iṣẹ àmi kan ni mo ṣe, ẹnu si yà gbogbo nyin. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Jesu dáhùn ó sì wí fún wọn pé, “Kìkì iṣẹ́ ààmì kan ni mo ṣe, ẹnu sì ya gbogbo yín. Faic an caibideil |