Johanu 6:34 - Yoruba Bible34 Wọ́n bá sọ fún un pé, “Alàgbà, máa fún wa ní oúnjẹ yìí nígbà gbogbo.” Faic an caibideilBibeli Mimọ34 Nigbana ni nwọn wi fun u pe, Oluwa, mã fun wa li onjẹ yi titi lai. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní34 Nígbà náà ni wọ́n wí fún un pé, “Olúwa, máa fún wa ní oúnjẹ yìí títí láé.” Faic an caibideil |