Johanu 3:30 - Yoruba Bible30 Dandan ni pé kí òun túbọ̀ jẹ́ pataki sí i, ṣugbọn kí jíjẹ́ pataki tèmi máa dínkù.” Faic an caibideilBibeli Mimọ30 On kò le ṣaima pọsi i, ṣugbọn emi kò le ṣaima rẹ̀hin. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Òun kò lè ṣàì máa pọ̀ sí i, ṣùgbọ́n èmi kò lè ṣàìmá rẹlẹ̀. Faic an caibideil |