Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 21:21 - Yoruba Bible

21 Nígbà tí Peteru rí i, ó bi Jesu pé, “Oluwa, eléyìí ńkọ́?”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

21 Nigbati Peteru ri i, o wi fun Jesu pe, Oluwa, Eleyi ha nkọ́?

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

21 Nígbà tí Peteru rí i, ó wí fún Jesu pé, “Olúwa, Eléyìí ha ńkọ́?”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 21:21
5 Iomraidhean Croise  

Nígbà tí Peteru bojú wẹ̀yìn, ó rí ọmọ-ẹ̀yìn tí Jesu fẹ́ràn tí ó ń tẹ̀lé e. Òun ni ó súnmọ́ Jesu pẹ́kípẹ́kí nígbà tí wọn ń jẹun, tí ó bi Jesu pé, “Oluwa, ta ni yóo fi ọ́ lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́ rí?”


Jesu dá a lóhùn pé, “Bí mo bá fẹ́ kí ó wà títí n óo fi dé, èwo ni ó kàn ọ́? Ìwọ sá máa tẹ̀lé mi ní tìrẹ.”


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan