Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 2:3 - Yoruba Bible

3 Nígbà tí ọtí tán, ìyá Jesu sọ fún un pé, “Wọn kò ní ọtí mọ́!”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

3 Nigbati waini si tan, iya Jesu wi fun u pe, Nwọn kò ni waini.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Nígbà tí wáìnì sì tán, ìyá Jesu wí fún un pé, “Wọn kò ní wáìnì mọ́.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 2:3
8 Iomraidhean Croise  

ati ọtí waini tí ń mú inú eniyan dùn, ati epo tí ń mú ojú eniyan dán, ati oúnjẹ tí ń fún ara lókun.


Oúnjẹ a máa múni rẹ́rìn-ín, waini a sì máa mú inú ẹni dùn, ṣugbọn owó ni ìdáhùn ohun gbogbo.


Ariwo ta lóde nítorí kò sí ọtí waini, oòrùn ayọ̀ ti wọ̀; ayọ̀ di àwátì ní ilẹ̀ náà.


Èyí ni ẹ̀jẹ̀ mi tí a fi dá majẹmu, ẹ̀jẹ̀ tí a ta sílẹ̀ fún ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ ọpọlọpọ eniyan.


Àwọn arabinrin mejeeji yìí ranṣẹ lọ sọ́dọ̀ Jesu pé, “Oluwa, ẹni tí o fẹ́ràn ń ṣàìsàn.”


Wọ́n pe Jesu ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sí ibi igbeyawo náà.


Jesu wí fún un pé, “Kí ni tèmi ati tìrẹ ti jẹ́, obinrin yìí? Àkókò mi kò ì tíì tó.”


Ẹ má ṣe jẹ́ kí ohunkohun dààmú yín, ṣugbọn ninu gbogbo adura ati ẹ̀bẹ̀ yín, ẹ máa fi àwọn ìbéèrè yín siwaju Ọlọrun pẹlu ọpẹ́.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan