Johanu 19:8 - Yoruba Bible8 Nígbà tí Pilatu gbọ́ gbolohun yìí, ẹ̀rù túbọ̀ bà á. Faic an caibideilBibeli Mimọ8 Nitorina nigbati Pilatu gbọ́ ọ̀rọ yi ẹ̀ru tubọ ba a. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Nítorí náà nígbà tí Pilatu gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀rù túbọ̀ bà á. Faic an caibideil |