Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 13:30 - Yoruba Bible

30 Lẹsẹkẹsẹ tí Judasi ti gba òkèlè náà tán, ó jáde lọ. Ilẹ̀ ti ṣú nígbà náà.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

30 Nigbati o si ti gbà òkele na tan, o jade lojukanna: oru si ni.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Nígbà tí ó sì ti gbà òkèlè náà tan, ó jáde lójúkan náà àkókò náà si jẹ òru.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 13:30
6 Iomraidhean Croise  

Nítorí wọn kì í lè é sùn, bí wọn kò bá tíì ṣe ibi, oorun kì í kùn wọ́n, tí wọn kò bá tíì fa ìṣubú eniyan.


Ẹsẹ̀ yín yá sí ọ̀nà ibi, ẹ sì yára sí àtipa aláìṣẹ̀. Èrò ẹ̀ṣẹ̀ ni èrò ọkàn yín. Ọ̀nà yín kún fún ìsọdahoro ati ìparun.


Ṣebí ojoojumọ ni mo wà pẹlu yín ninu Tẹmpili. Ẹ kò ṣe fọwọ́ kàn mí? Ṣugbọn àkókò yín ati ti aláṣẹ òkùnkùn nìyí.”


Jesu dáhùn pé, “Ẹni tí mo bá fún ní òkèlè lẹ́yìn tí mo bá ti fi run ọbẹ̀ tán ni ẹni náà.” Nígbà tí ó ti fi òkèlè run ọbẹ̀, ó mú un fún Judasi ọmọ Iskariotu.


Ẹsẹ̀ wọn yára láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan