Johanu 12:22 - Yoruba Bible22 Filipi lọ sọ fún Anderu, Anderu ati Filipi bá jọ lọ sọ fún Jesu. Faic an caibideilBibeli Mimọ22 Filippi wá, o si sọ fun Anderu; Anderu ati Filippi wá, nwọn si sọ fun Jesu. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní22 Filipi wá, ó sì sọ fún Anderu; Anderu àti Filipi wá, wọ́n sì sọ fún Jesu. Faic an caibideil |