Johanu 11:12 - Yoruba Bible12 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ fún un pé, “Oluwa, bí ó bá sùn, yóo tún jí.” Faic an caibideilBibeli Mimọ12 Nitorina awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ wi fun u pe, Oluwa, bi o ba ṣe pe o sùn, yio sàn. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Nítorí náà àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wí fún un pé, “Olúwa, bí ó bá ṣe pé ó sùn, yóò sàn.” Faic an caibideil |