Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 10:34 - Yoruba Bible

34 Jesu dá wọn lóhùn pé, “Mo ṣebí àkọsílẹ̀ kan wà ninu Òfin yín pé, ‘Ọlọrun sọ pé ọlọrun ni yín.’

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

34 Jesu da wọn lohùn pe, A kò ha ti kọ ọ ninu ofin nyin pe, Mo ti wipe, ọlọrun li ẹnyin iṣe?

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

34 Jesu dá wọn lóhùn pé, “A kò ha tí kọ ọ́ nínú òfin yín pé, ‘Mo ti wí pé, Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́’?

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 10:34
12 Iomraidhean Croise  

N óo máa yìn ọ́ tọkàntọkàn OLUWA, lójú àwọn oriṣa ni n óo máa kọrin ìyìn sí ọ.


Ọlọrun ti jókòó ní ààyè rẹ̀ ninu ìgbìmọ̀ ọ̀run; ó sì ń ṣe ìdájọ́ láàrin àwọn ẹ̀dá ọ̀run:


“O kò gbọdọ̀ kẹ́gàn Ọlọrun, o kò sì gbọdọ̀ gbé ìjòyè àwọn eniyan rẹ ṣépè.


Òun ni yóo máa bá ọ bá àwọn eniyan sọ̀rọ̀, yóo jẹ́ ẹnu fún ọ, o óo sì dàbí Ọlọrun fún un.


OLUWA bá dá Mose lóhùn pé, “Wò ó, mo ti sọ ọ́ di ọlọrun fún Farao, Aaroni, arakunrin rẹ ni yóo sì jẹ́ wolii rẹ.


Ìwé Mímọ́ kò ṣe é parẹ́. Bí Ọlọrun bá pe àwọn tí ó sọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ fún ní ọlọ́run,


Àwọn eniyan bi í pé, “A gbọ́ ninu òfin pé Mesaya wà títí lae. Kí ni ìtumọ̀ ohun tí o sọ pé dandan ni kí á gbé Ọmọ-Eniyan sókè? Ta ni ń jẹ́ Ọmọ-Eniyan?”


Èyí rí bẹ́ẹ̀ kí ọ̀rọ̀ tí a kọ ninu Òfin wọn lè ṣẹ pé, ‘Wọ́n kórìíra mi láìnídìí.’


Ninu òfin yín a kọ ọ́ pé òtítọ́ ni ẹ̀rí ẹni meji.


Ninu Òfin, ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, Oluwa wí pé, “N óo bá àwọn eniyan yìí sọ̀rọ̀ láti ẹnu àwọn eniyan tí ó ń sọ èdè àjèjì, ati láti ẹnu àwọn àlejò. Sibẹ wọn kò ní gbọ́ràn sí mi lẹ́nu.”


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan