Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 10:23 - Yoruba Bible

23 Jesu ń rìn kiri ní apá ọ̀dẹ̀dẹ̀ tí wọn ń pè ní Ọ̀dẹ̀dẹ̀ Solomoni ninu Tẹmpili.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

23 Jesu si nrìn ni tẹmpili, nì ìloro Solomoni.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

23 Jesu sì ń rìn ní tẹmpili, ní ìloro Solomoni,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 10:23
3 Iomraidhean Croise  

Ní àkókò òtútù-nini, ó tó àkókò Àjọ̀dún Ìyàsímímọ́ Tẹmpili tí wọn ń ṣe ní Jerusalẹmu,


Bí ọkunrin náà ti rọ̀ mọ́ Peteru ati Johanu, gbogbo àwọn eniyan sáré pẹlu ìyanu lọ sọ́dọ̀ wọn ní ọ̀dẹ̀dẹ̀ tí à ń pè ní ti Solomoni.


Ọpọlọpọ iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu ni àwọn aposteli ṣe láàrin àwọn eniyan. Gbogbo wọn wà ní ìṣọ̀kan ní ọ̀dẹ̀dẹ̀ tí wọn ń pè ní ti Solomoni.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan