Johanu 10:19 - Yoruba Bible19 Ìyapa tún bẹ́ sáàrin àwọn Juu nítorí ọ̀rọ̀ yìí. Faic an caibideilBibeli Mimọ19 Nitorina iyapa tun wà larin awọn Ju nitori ọ̀rọ wọnyi. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní19 Nítorí náà ìyapa tún wà láàrín àwọn Júù nítorí ọ̀rọ̀ wọ̀nyí. Faic an caibideil |